Take a fresh look at your lifestyle.

Owó Orí Ọjà Amẹ́ríkà Dẹ́rùba Ọrọ̀ Ajé Ilẹ̀ Adúláwọ̀ -Akọ́sẹ́mọsẹ́ Ọmọ Orílẹ̀-èdè Màláwì

Owó orí ọjà Amẹ́ríkà lórí ọrọ̀ ajé ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ sàkóbá bá ọrọ̀ ajé wọn, orílẹ̀-èdè Màláwì jẹ́ ọ̀kan, akọ́sẹ́mọ́sẹ́ nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú-Maclan Kanyang’wa sọ èyí. Ó sọ pé, oye owó tí wọ́n ń ta nǹkan…

Ènìyàn Ẹgbẹ̀rún Mẹ́rìndínlọ́gọ̀ta Ló Ti Lùgbàdí Àìsàn Ibà Láti Oṣù Kẹwàá Ní Orílẹ̀-èdè Nàmíbíà

Ènìyàn ẹgbẹ̀rún Mẹ́rìndínlọ́gọ̀ta tó lé ọgbọ̀nlélọ́gọ̀rún(56,130) ló ti lùgbàdí àìsàn ibà tí márùndínlọ́gbọ̀n ènìyàn sì ti kú láti ìgbà tí àìsàn nàá ti ń sọsẹ́ láti oṣù Kẹwa ọdún 2024, bí Mínísítà ètò ìlera Esperance Luvindao ṣe…

Alága Ẹgbẹ́ òṣèlú APC Ìpínlẹ̀ Kebbi Sọ Pé Gómìnà Kò Yalọ Ẹgbẹ́ Míràn.

Alága Ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), Ìpínlẹ̀ Kebbi, Abubakar Muhammad Kana ti ṣẹ́ àhesọ lórí ẹ̀rọ ayélujára pé Gómìnà Nasir Idris fẹ́ sálọ sínú ẹgbẹ́ òṣèlú míràn. Nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀ níbi Ìpàdé alẹ́nulọ́rọ̀ ẹgbẹ́ APC kan…

SGF Gba Àwọn Adarí Ẹ̀sìn Níyànjú Láti Ní Ẹ̀mí Ìpamọ́ra Àti Ìṣọ̀kan Fún Orílẹ̀-èdè

Àti Ìṣọ̀kan Fún Orílẹ̀-èdè Akọ̀wé ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (SGF), George Akume Abuja ti rọ àwọn olórí ẹ̀sìn láti darapọ̀ mọ́ ìjọba àpapọ̀ ní ọ̀nà láti so ètò ààbò lé dain-dain àti kí wọn sì wà ní ẹ̀mí ìṣọ̀kan pẹ̀lú ètò ìrètí ọ̀tun…
button