Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Gbéra Láti Abùjá Lọ Ṣì Ìpínlẹ̀ Anambra Fún Ṣíṣí Àwọn Àkànṣe Iṣẹ́

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti gbéra lọ sí Ìlú Awka ti ṣe Olú ìlú ìpínlẹ̀ Anambra fun ṣíṣí àwọn àkànṣe iṣẹ́ . Ní ìlú Akwa, ààrẹ Tinubu yóò sì àwọn àkànṣe iṣẹ́ ti ijọba gómìnà Chukwuma Soludo ti ṣe. Àwọn akanse iṣẹ ti ààrẹ fẹ sí ní ìpínlẹ̀…

Ìrìn Àjò Sí Ilẹ̀ Mímọ́ Hajj: Gómìnà Makinde Rọ Àwọn Arìnrìn Àjò Láti Gbàdúrà Fún Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Àti…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí pé gbogbo ọmọ Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tó bá fẹ́ rin ìrìn àjò Hajj ni ọdún 2026 ni yóò máa gbéra láti Pápákọ̀ òfurufú Ladoke Akintola tó wà ní agbègbè Alakia ní ìlú Ìbàdàn tààrà lọ sí ilẹ̀ Sáúdí…
button