UNICEF Gbóríyìn Fún Ìjọba Ìpínlẹ̀ Adamawa Fún Ìfọ́wọ́ Sí Òfin Ìdáàbòbò Àwọn Ọmọdé
Àjọ Àgbáyé fún Àwọn ọmọdé (UNICEF) tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí gbóríyìn fún Gómìnà Ìpínlẹ̀ Adamawa, Ahmadu Fintiri fún ìfọ́wọ́ sí ìwé-àṣẹ Ìdáàbòbò àwọn ọmọdé sínú òfin ìpínlẹ̀ náà.
Ìyìn náà wà nínú ọrọ̀ kàn tí Arábìnrin Cristian…