Èmi Yóò Gbé Ìjọba Sílẹ̀ Lọ́dún Tó Ń bọ̀ – Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣé Ìdánilójú Fún Àwọn Àrà Ìlú
Ààrẹ Muhammadu Buhari ní ọjọ́ Ajé tún ṣé àdéhùn rẹ̀ láti gbé ìjọba lé ẹní tí wọ́n bá fí ibo Yan gẹ́gẹ́ bí ààrẹ lọ́wọ́ ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún tó ń bọ̀, ó sọ pé àsìkò rẹ̀ yóò dópin lọ́jọ́ yẹn ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìlànà…