Ààrẹ Muhammadu Buhari tí dé sí ìpínlẹ̀ Sokoto fún àbẹwò ọlọjọ kàn lẹ́nu iṣẹ́
Ààrẹ náà ní Gómìnà Ìpínlẹ̀ náà Aminu Tambuwal, kí káàbọ̀ ní pápákọ̀ òfurufú Abubakar Sa’ad III tí ìlú Sokoto ní nkán bí àgó mẹ́wàá òwúrọ̀ (10.40 GMT).
Ààrẹ tèsíwájú látí ṣé àbẹwò sí ààfin Sultan tí Sokoto, ìyẹn Olóyè Abubakar Sa’ad III.
Ní kété lẹyìn náà ní yóò jẹ́ àlejò pàtàkì níbí Àpéjọ Àwọn Òṣìṣẹ́ Ọmọ Ògún tí ọdún yìí, èyí tí yóò ṣíṣọ̀ lójú éégun rẹ̀.
Àwọn ẹlẹṣọ ààbò tí wá ní sẹ́pẹ́ ní olú-ìlú ìpínlẹ̀ náà tí àwọn tí yóò kópa nínú àpéjọ náà jẹ́ Ọ̀gá nínú àwọn ẹṣọ ọmọ ogún Nàìjíríà.
Àpéjọ náà ní a ní ìrètí látí pèsè ayé fún àwọn òṣìṣẹ́ ààbò látí ṣé àtúnyẹwò àwọn ìlànà wọ́n àti pàápà àwọn ìmọ tuntun ní ogún látí kojú ipaniyan lọ́nà tó lòdì sí òfin àti àwọn italaya ààbò mìíràn.
Ààrẹ Buhari yóò padà sí Abuja loni náà.