Take a fresh look at your lifestyle.

NSF: Ìpínlẹ̀ Delta Lo Ń Léwàjú Tí Ìpínlẹ̀ Ogun Sí Ń Tọ Lẹ́yìn

0 160

Ayẹyẹ èrè ìdárayá tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà òní ọdún ikọkanlelogun ìrù rẹ̀ (21st), tá pé ní Delta 2022, ló ń tẹ̀ síwájú bí ìpínlẹ̀ Delta tí ń gbégbá orókè lórí tábìlì àmì ẹyẹ, nígbàtí ìpínlẹ̀ Ogun àti Ọyọ ńlẹ̀lé lẹyìn lóri akasọ náà.

Ìpínlẹ̀ Delta lo fakọyọ jùlọ níbí ayẹyẹ aṣe kẹyin tí o sí tún ti ń léwájú lórí tábìlì àmì ẹyẹ, látí ibẹrẹ ìdíje náà.

Èyí ló ń farahàn bí àwọn ìpínlẹ̀ bí Ábíá, Bayelsa, Edo tí ṣé tí ń sápá takuntakun níbí ìdíje naa

Tábìlì àmì ẹyẹ yìí ni a gbà kalẹ̀ nibi ìdíje náà ní ọjọ kẹrin oṣù Kejìlá,ọdún 2022 ni déédé agogo Marun-un irọlẹ.

Lekan Orenuga

Leave A Reply

Your email address will not be published.