Take a fresh look at your lifestyle.

Iná Bẹ̀sílẹ̀ Ní South Korea, Sọ́ Ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀ta Ènìyàn Dì Aláìnílélórí Ní Guryong

Ó fẹ́rẹ̀ tó Ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀ta (500) àwọn ènìyàn ní a yọ̀ kúrò ní ilé wọ́n ní ọjọ́ Ẹtì lẹyìn tí ìnà ṣẹ̀lẹ̀ ní abúlé Guryong. Gẹ́gẹ́ bí ìròyìn ṣé sọ, kò tíì sí ẹní tó pàdánù ẹ̀mí rẹ̀, bẹ́ẹ̀ní ẹnikẹni kò fí àrà pàá. Fanran kàn lórí ayélujára…

Àwọn Òṣìṣẹ́ Ojú-pópó Orílẹ̀-èdè Senegal Yànṣẹ́ Lòdì Lórí Ààbò Ojú Ọ̀nà

Ẹ̀ka ìrìna tí Orílẹ̀-èdè Senegal pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ lẹ́kà náà tí darapọ̀ lórí iyànṣẹ́ lòdì látí takò ìgbésẹ ìjọba látí dẹkùn àwọn ìjàmbá ojú pópó. Èyí ló wáyé lẹ́yìn ìjàmbá ọkọ tó ṣẹ̀lẹ̀ ní Kaffrine. Ṣùgbọ́n, àpá kàn nínú àwọn olufẹhonu…

Ìjọba Nàìjíríà Ṣọ́nà Látí Pèsè Ilé Gbígbé Fún Àwọn Aráàlú

Ìjọba Nàìjíríà sọ pé òun yóò máa tẹ̀ síwájú láti ṣé ànfàní fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ní orílẹ̀-èdè náà ní pàtàkì jùlọ, ilé ìgbé lọ́pọ̀ yanturu. Olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba tí Orílẹ̀-èdè yìí, Folashade Yemi-Esan ló sọ èyí níbí ayẹyẹ ìpèsè ilé…

Wọ́n Rọ́ ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Láti Ṣàyẹ̀wò Òṣèlú Ẹlẹyàmẹ̀yà Láàrín Àwọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba

Olórí àwọn òṣìṣẹ́ nígbà kàn rí ní Ìpínlẹ̀ Kwara, Àárín gbùngbùn àríwá Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Alhaji Mudi Adebayo Gold, tí kesi ìjọba àpapọ̀ látí bojuwò èwù òṣèlú ẹlẹyàmẹ̀yà láàrín àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba tí wọ́n ń tẹlé àwọn olóṣèlú nítorí òwò àti…

2023 AFRD: Ààrẹ Buhari, Mínísítà Fún Ààbò Bú Ọlá Fún Àwọn Akínkanjú Tó Ṣubú Lógún

Mínísítà fún ètò ààbò Major General Bashir Magashi (rtd) darápọ̀ mọ́ ọgá àgbà fún àwọn ọmọ ogún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ààrẹ Muhammadu Buhari láti fí ìsàmì le'lẹ sí National Arcade Abuja, lásìkò tí orílẹ̀-èdè yìí ń ṣé ayẹyẹ ìrántí Ológun ti…

Olórí Àlatakò Orílẹ̀-èdè Tanzania Yóò Ní Ànfààní Fí Òpin Sí Ọjọ́ Rẹ̀ Lẹyìn Òdí Ìlú

Olórí àlatakò Tanzania àtí olùdíje Ààrẹ tẹlẹ rí Tundu Lissu tí sọ pé òun yóò pàdà sí ilé ní oṣù yìí látí ẹ̀yìn odi ìlú látí “tún ìtàn ìlú náà kọ̀" lẹyìn ìpinnu ìjọba látí fí ayé gbà àpéjọ àwọn olóṣèlú. Ààrẹ Samia Suluhu Hassan yí ofin…
button