Ẹ̀ka ìrìna tí Orílẹ̀-èdè Senegal pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ lẹ́kà náà tí darapọ̀ lórí iyànṣẹ́ lòdì látí takò ìgbésẹ ìjọba látí dẹkùn àwọn ìjàmbá ojú pópó. Èyí ló wáyé lẹ́yìn ìjàmbá ọkọ tó ṣẹ̀lẹ̀ ní Kaffrine.
Ṣùgbọ́n, àpá kàn nínú àwọn olufẹhonu hàn takò bí wọ́n ṣé kùnà láti ṣé ìjíròrò àtí áìlètò tó múná dóko.
Ó kéré jù, ènìyàn mọkandinlogun (19) ló pàdánù ẹ̀mí wọ́n nínú ìjàmbá ọkọ ní ọjọ́ Ajé, tí o sí sọ ìyè ẹ̀mí tó nù nínú ìjàmbá ọkọ dì ọgọ́ta (60) láàrín ọjọ́ díẹ̀.
Tún kà nípa: Àdó Olóró Ń Ró Lákọlákọ Ní Ibùdó Ológun Ní Orílẹ̀-èdè Somalia
Ẹ̀wẹ̀, Ìjọba tí kéde àwọn òfin ìrìna oríṣiríṣi. Lára wọ́n ní; fí fòfin dè ìgbé tàyà wọ́lè èyí tó ṣé òkùnfà ìjàmbá ọkọ tí ọsẹ tó kọjá, ìrìna ọkò akero lálẹ̀ àtí bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ́.
Gẹ́gẹ́ bí Banki Àgbáyé ti sọ, Senegal, orílẹ̀-èdè tí ó kéré ní mílíọ̀nù mẹ́tàdínlógún (17 million), ṣàkọsílẹ̀ ìjàmbá ọkọ̀ mẹ́rìnlélógún (24) fún àwọn ènìyàn ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọrùn (100,000) olùgbé orílẹ̀-èdè náà lọ́dọọdún.
Lekan Orenuga
Leave a Reply