Take a fresh look at your lifestyle.

Okocha Àtí Mikel Bá Orílẹ̀-èdè Turkey Kẹ́dun Lórí Ìṣẹ̀lẹ̀ ìwárírì-ilẹ̀ Tó Ṣẹlẹ̀

Àwọn àgbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹlẹ, Austin Okocha àti Mikel Obi tí darapọ̀ mọ́ àwọn ènìyàn látí fí ikẹdun wọ́n ránṣẹ́ sí àwọn ẹbí àwọn tó pàdánù ẹ̀mí wọ́n àtí àwọn tó fí ará pá nínú ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Turkey láìpẹ́ yíì.…

Ẹ̀ka Ọkọ̀ Òfurufú Nàìjíríà Gbà Owó Tó Lé Ní Ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀rin Mílíọ̀nù Náírà Fún Ìtọ́jú Pápákọ̀

Ilé-iṣẹ́ Òfurufú tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ọjọ́rú gbá ibuwọlú ìwé iṣẹ́ àkànṣe tí ó tó ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀rin lé lógún mílíọ̀nù Náírà N721m fún ìtọ́jú Pápákọ̀ Òfurufú Aminu Kano International ní Ìpínlẹ̀ Kano, Àríwá Ìwọ̀-oòrùn tí orílẹ̀-èdè yìí tí…

Ètò Ìdìbò: BVAS Yóò Rán Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Yí Lọ́wọ́ Látí Yàn Olórí Tí Wọ́n Fẹ́ Sípò – DG VON

Olùdarí Àgbà tí Voice of Nigeria, VON, Osita Okechukwu sọ pé pèlú ìfilọ́lẹ̀ ètò ìforúkọsílẹ àwọn olúdìbò (Bimodal Voters Accreditation System) BVAS, àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò yàn olubori nínù ètò ìdìbò gbogbogbò 2023. DG sọ èyí…

Ìṣòro Owó/Èpò: Gómìnà Makinde Dá Àwọn Ọkọ Àkérò Ọ̀fẹ́ Sí Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Gómìnà Seyi Makinde tí ìpínlẹ̀ Ọyọ tí kéde àwọn ọkọ Àkérò Omituntun Mass Transit ọ̀fẹ́ látí mú ìrọ̀rùn bá àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà. Èyí ní ó kéde látàrí ìdààmú ònìbejì tí owó náírà àtí àìtó èpò tó tí dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lagada…

Ọmọ Obìnrín Ọdún Mẹ́wàá Orílẹ̀-èdè China Nọ́wọ́ Sí Ilé Ọmọ Aláìníyà Kàn Ní Abùjá

Ọmọbìnrin ọmọ ọdun mẹ́wàá kàn tí Orílẹ̀-èdè China WEI/YUE CHEN, ti ṣé itọrẹ àánù àwọn òun èlò oúnjẹ àti àwọn òun èlò ilé sí Destined Children's Orphanage ní Abuja, Olú-ìlú Nàìjíríà. Ọmọdébìnrin náà nígbà tó ń gbé àwọn nǹkan náà lọ́…

Ẹ́ Fí Àyè Gbá Àwọn Aṣojú-Owó Látí Wá Ojútùú Sí Owó Tuntun – Ìgbákejì Ààrẹ Pàrọ̀wá Fún Àwọn…

Ọnà sí ìṣòro tí àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń kojú lórí owó tuntun ní kí Bánkì gbogbogbò orílẹ̀-èdè yìí (Central Bank of Nigeria CBN) àtí àwọn Bánkì Ìṣòwò (Commercial Banks) fí ayé púpọ̀ díẹ̀ síì gbà àwọn aṣojú owó àti FinTech látí kojú…
button