Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Yìí Rọ́ Àwọn Àdári Ilé-ẹ̀kọ́ Gíga Nàìjíríà Látí Ṣé Ìpolongo Ilé-ìwé Wọ́n

Ìgbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo tí rọ́ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga ní Nàìjíríà látí ṣiṣẹ́ takuntakun fún ìgbéga àtí ọnà àtí máà gbá owó wọlé fún àwọn ilé-ẹ̀kọ́ wọnyí nítori wípé kò sí Orílẹ̀-èdè kàn lágbayé tó lé ṣé ètò…

Ààrẹ Buhari kí Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun Kú Ọjọ́-ìbí ọdún mẹ́tàlélọ́gọ́ta [63]

Ààrẹ Muhammadu Buhari ń yọ pẹ̀lú Gómìnà Ademola Nurudeen Adeleke tí Ìpínlẹ̀ Osun níbí tó tí ń ṣé ayẹyẹ ọjọ́-ìbí ọdún mẹ́tàlélọ́gọ́ta rẹ̀ tó ń bọ̀ ní ọjọ́ kẹtala oṣù kàrún (May 13, 2023). Ààrẹ náà gbàgbọ́ pé ifarabalẹ ojú tútù Adeleke…

Àwọn Ọlọ́pàá Nàìjíríà Mú Àwọn Àjínígbé Ní Ìpínlẹ̀ Kano

Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá tí Ìpínlẹ̀ Kano tí fí ọwọ́ òfin mú àwọn àjínígbé mẹrindinlogun (16) tí wọ́n fúnra sí láàrín gbùngbùn Kano àtí àwọn àgbègbè ìjọ̀ba ìbílẹ̀ mìíràn ní Ìpínlẹ̀ náà. Kọmiṣanna Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ náà Mohammed Usaini Gumel sọ èyí…

Ìpínlẹ̀ Kogi Fọwọ́sí Ọjọ́-orí Ìfẹyìntì Túntún Fún Àwọn Olùkọ

Ilé-ìgbìmọ̀ Ìpínlẹ̀ Kogi tí fọwọ́sí Ọdún márùn dín làádọ́rin 65 gẹ́gẹ́ bí Ọjọ-ori Ifẹyinti tí àwọn olùkọ Ìpínlẹ̀ àtí àwọn nkán tó jọmọ, 2022 ní Ọjọ́bọ̀ 11th May. Agbẹnusọ tí Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin náà, Matthew Kolawale, làkókò tó ń ṣàlàyé…

Orílẹ̀-èdè Gẹẹsi Ní Orílẹ̀-èdè Àkọkọ́ Látí Pèsè Òun Ìjà Olóró Ọlọna Gigun Fún Orílẹ̀-èdè Ukraine

Orílẹ̀-èdè Gẹ́ẹ̀sì ní Ọjọ́bọ̀ dì orílẹ̀-èdè àkọkọ́ látí bẹ̀rẹ̀ sí pèsè fún Ukraine pẹ̀lú àwọn misaili òun ìjà ọlọna gígùn, èyítí yóò ràn àwọn ọmọ ogún Ukraine lọwọ́ látí kojú àwọn ọmọ ogún Russia. Ukraine tí n béèrè fún àwọn òun ìjà…

Àwọn Ọmọ Ilé-ìwé Mẹsán Pàdánù Ẹ̀mí Wọ́n Nínú Ìjàmbá Ọkọ Ojú-Omí Ni Ghana

Àwọn ọmọ ilé-ìwé mẹsán tí pàdánù ẹ̀mí wọ́n ní àgbègbè Greater Accra tí Orílẹ̀-èdè Ghana, lẹ́yìn tí ọkọ ojú-omí tó ń gbé wọ́n lọ sí ilé-ìwé rì. Awọn ọmọde náà ní ọjọ́ orí wọ́n wà láàrín ọdún Mẹ́jọ̀ sí Mẹ́ẹ̀dógún ní wọ́n sọ pé wọ́n rìn…

Látàrí Wàhálà Sudan: NEMA Rá Áwọn Nkán Oúnjẹ Ránṣẹ́ Sí Áwọn Ọmọ Nàìjíríà

Àjọ tó n gbógun tí ìṣẹ̀lẹ̀ pájáwìri tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, NEMA, tí fí àwọn onírúurú oúnjẹ tí a fọwọsi fún Ilé-iṣẹ́ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Sudan ránṣẹ́ ní Ọjọ́bọ̀ látí pèsè fún àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n n dúró fún ọkọ Òfurufú…
button