Take a fresh look at your lifestyle.

NMDPRA Ṣé Ìpolongo Lílò Gaasi Fún Ìdàgbàsókè Àwọn Ilé-iṣẹ́ Àtí Àyíká Mímọ

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 225

Àjọ Nigeria Midstream and Downstream Petroleum Regulatory Authority (NMDPRA), tí kepè sí àwọn oníbárà ilé-iṣẹ́ tí epó-rọ̀bì disu (diesel) látí ṣé igbalaye fún lílò gaasi nítorí pé o jẹ́ orísun àgbàrá jùlọ, tó sì ṣé idínwó fún ìdàgbàsókè àwọn ilé-iṣẹ́.

Ọgá àgbà NMDPRA, Farouk Ahmed ló pé ìpe yi níbí ìpàdé ọlọjọ kàn pẹ̀lú àwọn alẹnu-lọrọ lórí lílò Gaasi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó wáyé ní Bristol Palace Hotel ní ìpínlẹ̀ Kano, Nàìjíríà.

Ahmed sọ pe, Ó tí ń dì dandan fún àwọn ilé ìṣẹ́ nlá nlá tó ń ẹ̀rọ amunowa disu látí gbá lílò gaasi èyí tí Orílẹ̀-èdè yìí tí faramọ lílò rẹ̀.

Tún kà nípa: Ẹ Se Àtúnṣe Òpópónà Láti Dènà Ìjàm̀bá Lásìkò Òjò- Ẹgbẹ́ Awakọ̀ Epo Rọ̀bì Pàrọwà Sí Ìjọba

Ó sọ pé ibaraẹnisọrọ pẹ̀lú àwọn alẹ́nu-lọ̀rọ̀ yií yóò jẹ́ kí ipolongo ètò gbòòrò sí, yóò sì tún mú kí àwọn ilé ìṣẹ́ wọnyí tẹ̀lé àṣà yìí ni ìbámu pẹ̀lú ọnà àtí wá ojútùú sí àwọn ìpenija àyíká wà ní Orílẹ̀-èdè yìí.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button