Nàìjíríà Yòó Ṣé Àtilẹ́yìn Ìbáṣépọ̀ Àgbáyé Fún Ètò Ẹ̀kọ́
Mìnísítà Ìpínlẹ̀ fún ètò Ẹ̀kọ́, Dókítà Yusuf Sununu, sọ pé Ìjọba tí ṣétan láti ṣé àtilẹ́yìn Ajọṣépọ̀ Àgbáyé Fún Ẹ̀kọ́, GPE, látí ṣé àṣéyọrí ìdágbàsóké ní ẹ̀ká nàá.
Sununu sọ èyí ní ilé-iṣẹ́ rẹ̀ ní Abuja Nígbà tó padé pẹ̀lú àwọn òṣíṣẹ́…