Take a fresh look at your lifestyle.

Iraq Bẹ̀rẹ̀ Kíkó Àwọn Oníjà Kurdish Iran Kúrò

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 164

Iraq tí bẹ̀rẹ̀ kíkó àwọn oníjà Kurdish Iran pàdà látí àwọn àgbègbè Kurdish Iraq pẹ̀lú Iran sí àwọn ibùdó tó jìnnà sí ààlà gégébí àdéhùn ààbò láàrín Baghdad àti Tehran, Mínísítà ilẹ̀ Òkèèrè, Fuad Hussein sọ.

Iraq àtí Iran fọwọ́sí ìwé adehun ààbò ààlà ní Oṣù Kẹta, ìgbésẹ tí wọ́n gbé látí dáàbòbo àwọn ààlà orílẹ̀-èdè méjèèjì.

Hussein sọ pé òun yóò ṣàbẹwò sí Tehran ní Ọjọ́bọ́ látí fí ọrọ̀ náà tó wọ́n létí látí ríi dájú pé kó dá ikunsinu sílẹ̀.

Leave A Reply

Your email address will not be published.