Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Aṣòfin Nàìjíríà Yóò Tẹ̀síwájú Nínú Àjọṣepọ̀ Ìdàgbàsókè Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Kenya

Ilè Ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣofin yóò tẹ̀síwájú nínú àjọṣepọ̀ wọ́n pẹ̀lú Kenya lórí ìdàgbàsókè àwọn apá pàtàkì tí ètò-ọrọ àjé. ‎ ‎ Alága, Ẹgbẹ́ Ilé aṣòfin Orílẹ̀-èdè méjèèjì, Ọ̀gbẹ́ni Abdullahi El-rasheed, fúnni ní ìtọ́kasí ní ìpàdé kán pẹ̀lú…

Àwọn Olókìkí Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣètọrẹ Fún Iṣẹ́ Ìkọlé Ìkàwé Ààrẹ Babangida

Àwọn olókìkí ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣètọrẹ sí ilè ìkàwé Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí Ibrahim Badamosi Babangida, láti wà ní Minna, Ìpínlẹ̀ Niger. ‎ ‎ Ọjọ́bọ̀ ní wọ́n ṣé ìfilọ́lẹ̀ ìwé Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí náà, ìtàn-àkọọlẹ tí Ààrẹ ológun tí wọ́n pé àkọlé…

Ààrẹ Tinubu F’ọwọ́sí Ìdásílẹ̀ Àwọn Ilé-ẹ̀kọ́ Gíga Tí Ìjọba Àpapọ̀ Ní Osun, Ekiti

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí fọwọ́sí àwọn ìwé àbádófin méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí yóò ṣé ìdásílẹ̀ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí ìjọba àpapọ̀ Yunifásítì lórí ètò ẹ̀kọ́ ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè (Federal University of Agriculture and Development Studies) ní…

Ètò Ẹ̀yawó Àwọn Ọmọ Ilé-ìwé Tí 2024/2025 Yóò Bẹ̀rẹ̀ Ní Oṣù Kejì, Ọdún Yìí

Ètò ẹ̀yawó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà 'Nigeria Education Loan Fund NELFUND', ní wọ́n yóò faye gbá ìforúkọsílẹ̀ fún tí ọdún 2024/2025 yóò bẹ̀rẹ̀ ọjọ́ kejìlélogún, Oṣù Kejì, Ọdún 2025. ‎ ‎ Wọ́n tún sọ pé tí ọdún 2023/2024 ní yóó wá…

Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣé Ìlérí Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Obìnrin Àti Ọdọ

Àyá Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Oluremi Tinubu sọ pé òún tí pinnu látí ṣé ìpolongo, koriya àti ìdásílẹ̀ àwọn àjọṣepọ̀ tí yóò fún àwọn obìnrin àti àwọn ọdọ Nàìjíríà ní àgbàrá láti ṣiṣẹ́. ‎ ‎ O n sọrọ yíi l'àkókò Àpéjọ Gbogbogbò tí…
button