Take a fresh look at your lifestyle.

Àpèjọ oúnjẹ àgbáyé: Igbákejì ààrẹ Nàìjíríà yóò se ìjíròrò pàtàkì lórí rẹ̀

Àwọn tó nííṣe ní abala ètò ọ̀gbìn yoo péjọ ní Iowa, orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, fún àpéjọ oúnjẹ káríayé, tí igbákejì ààrẹ Nàìjíríà Kashim Shettima yóò sọ̀rọ̀ pàtàkì lórí rẹ̀ leyii ti yoo waye ní ọjọ́…

Ẹjọ́ kò tẹ́milọ́rùn Ìbò ààrẹ: PDP nírètí pé òun yóò yege ní ilé-ẹjọ́ tó ga jùlọ

Ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò Nàìjíríà, Peoples Democratic Party, PDP, ti sọ pé ó dá òun lójú pé ilé-ẹjọ́ tó ga jùlọ yóò ṣe ìdájọ́ òtítọ́ bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ ìgbẹ́jọ́ kò tẹ́milọ́rùn ẹ̀yìn Ìbò ààrẹ  2023. Akọwe apapọ…

Ìpínlẹ̀ Sokoto: UDUTH Se ìtanijí fún ará ìlú lórí ewu tó wà nínú ààrùn ọgbẹ́ ọ̀fun

Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìlera Fáfítì Usmanu Danfodiyo (UDUTH), ìpínlẹ̀ Sokoto ti ṣàgbékalẹ̀ ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ìtanijí ọlọ́jọ́ kan fún gbogbo ará ìlú lórí ewu tó wà nínú ààrùn ọgbẹ́ ọ̀fun. Ninu ọrọ rẹ lasiko ayẹyẹ…
button