Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Ebonyi yóò fa àwọn ilé-ìwé ìjọba lé ilé ìjọsìn lọ́wọ́

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ebonyi ti ṣetán láti dá àwọn ilé ìwé tí ó jẹ́ ti ilé ìjọ́sìn tẹ́lẹ̀ tí ìjọba gbà, padà fún àwọn tí ó nií, kí ó tó di ìparí ọdún yìí. Gomina ipinlẹ Ebonyi, Ọgbẹni Francis Nwifuru ṣe ipinnu yii…

Adarí ilé ìgbìmọ̀ pinnu pé àlàáfíà yóò túnbọ̀ jọba ní ìpínlẹ̀ Akwa Ibom

Adarí ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nàìjíríà tí ó tún jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom nígbà kan rí, Godswill Akpabio, ti túnbọ̀ fi ìdí ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ láti wá àlàáfíà àti ìdàgbàsókè fún ìpínlẹ̀ Akwa Ibom,…

Adarí Nàìjíríà ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí, Jonathan fún ọjọ́ ìbí ọdún…

Adarí Nàìjíríà, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, ti ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí Goodluck Ebele Jonathan fún ọjọ́ ìbí ọdún kẹrìndín-láàdọ́rin rẹ̀. Wọn bi Aarẹ tẹlẹ rí Goodluck, ti o ṣejọba lati ọdun 2010 si 2015, ni ogunjọ,…

ARD fún ìjọba Enugu ní ìparí ìpinnu ọjọ́ mẹ́rìnlá láti gba àwọn Dókítà si

Ẹgbẹ́ àwọn Dókítà Àdúgbò (ARD) ti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Fáfítì ti Ìmọ̀ Sáyẹ́ńsì àti Ìmọ̀ Ẹ̀rọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ ìwòsàn (ESUTH), ti fún ìjọba Enugu ní ìparí ìpinnu ọjọ́ mẹ́rìnlá láti gba àwọn Dókítà si iṣẹ síi,kí…
button