Ìyáàfin Soludo rọ àwọn tó nííṣe láti dásí ìfòpin sí ìwà ipá lórí àwọn obìnrin
Ìyàwó gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ìyáàfin Nonye Soludo, ti ṣàlàyé pé gbogbo àwọn tó nííṣe ní láti dìde tí wọ́n bá fẹ́ kí akitiyan láti fòpin sí ìwà ipá lórí àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ bìnrin so èso rere.…