Alákóso ilé-ẹ̀kọ́ gíga OAU gbèrò ẹ̀kúnwó Fún Àwon ilé-ẹ̀kọ́ gíga Nàìjíríà
Alákóso Fáfítì Ọbáfémi Awólọ́wọ̀, ọ̀jọ̀gbọ́n Èyítọ́pé Ògúnbọ́dẹdé ti képè fún ẹ̀kúnwó ìṣàkóso àwon ilé ìwé gíga Nàìjíríà.
Ọ̀jọ̀gbọ́n Ogunbọdẹde pe ìpè náà ní Èkó, lákòókò ti wọn n ṣàgbékalẹ̀ the Great…