Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ènìyàn méjìlé-láàdọ́ta míràn tún ti ní ààrùn còrónà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

72

Nàìjíríà tún ti rí àwọn ènìyàn méjìlé-láàdọ́ta míràn tó kó ààrùn còrónà jákèjádò orílè-èdè.

Ile-iṣẹ to n mojuto ajakalẹ aarun lorilẹ-ede (NCDC ),ni o kede eyi lorii bo ṣe n lọ.Awọn eniyan tuntun wọnyii jẹyọ ni awọn ipinlẹ meje .

Ipinlẹ Rivers (ogun) , Eko-(mẹẹdogun), Plateau-(mejọ), Jigawa(mefa), Delta-(ẹyọkan), Gombe-(ẹyọkan), Kaduna-(ẹyọkan).

Lọwọlọwọ bayii,eniyan ẹgbàájì- le- ni- ọ̀kẹ́- mẹ̀wá- abọ- o- din ni- ẹ̀ta- le – l-okòó lo ti ko aarun ọhun,

ẹ̀ẹ́dẹ́gbàrin- le- ni- ọ̀kẹ́- mẹ̀wá- o- din-  lẹ̀ta eniyan ti gba iwosan,ti ẹ̀rin-din-ni-ojì din ni ẹgbẹ́ẹ́ẹdógún eniyan si ti jepe oluwa.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.