Take a fresh look at your lifestyle.

Ìrọ̀rùn dé bá gbígba ìwé irinnà sí orílẹ̀-èdè UK

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

74

Ìjọba àpapọ̀ ní ọjọ́ ìṣẹ́gun tún fìdí ìpinnu rẹ̀  múlẹ̀ láti mú ìlànà àti gba ìwé ìrìnnà fún àwọn ọmọ Nàìjíríà nílé àti lókè òkun dìrọ̀rùn , bí ó ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ àtúnṣe ìwé ìrìnnà  tuntun náà.

Minisita fun ọrọ abẹle, ọgbẹni Rauf Arẹgbẹsọla, sọ eleyi di mimọ  ni ọjọọbọ nibi ipolongo iwe irinna lori ayelujara ni ọfiisi orile-ede ni  London, United Kingdom.

Minisita sọ pe,  iwe irinna Naijiria jẹ nnkan ti ijọba gbọdọ pese ati ri gba laisi wahala eyikeyi,ni asiko ti ko si pẹ rara.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.