Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè South Áfíríkà ṣe Ìfilọ́lẹ̀ àjọ ìgbógunti Ìṣíwá Ní Dọ́bánù

Ọgọọgọ̀rún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Operation Dudula kóra wọn jọ ní òpópónà Dọ́bánù, tí wọ́n sì ń bèèrè pé kí ìjọba gbé ìgbésè tó lágbára láti kojú àwọn ọgọ́ọ́rọ àwọn ènìyàn tí ń ṣíkiri lọ́nà  àìtọ́. Awọn…

Àwọn amòye ń gbèrò ààbò tó péye Fún Ìpèsè Oúnjẹ lórílẹ̀-èdè

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn amòye ní ẹ̀ka iṣẹ́ ọ̀gbìn àti káràkátà ti ń gbàá níyànjú láti ri pé orílẹ̀-èdè bọ́ lọ́wọ́ àwọn ogun abẹ́lé àti àìsààbò tó ń jàá kí ó fi le ṣe iṣé ọ̀gbìn débi tólámì. Eyi ni idi ti…

Olùdarí àgbà fún àjọ àgùnbánirọ̀, NYSC kìlọ̀ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ láti yàgò fún…

Olùdarí Àgbà fún ẹgbẹ́ àgùnbánirọ̀, (NYSC) ní orílè-èdè Nàìjíríà,ajagun Shuaibu Ibrahim, ti kìlọ̀ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ láti máá ṣe lọ́wọ́sí ọ̀rọ̀ òṣèlú gẹ́gẹ́ bí ìdìbò gbogboogbo ọdún 2023 ti ń súnmọ́.…
button