Take a fresh look at your lifestyle.

Macron, Le Pen gbégbá orókè nínú ìpele kìnní ìdìbò ààrẹ orílẹ̀-èdè Faransé

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 199

Ààrẹ Faransé lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, Emmanuel Macron àti ẹnìkejì rẹ̀, Marine Le Pen ni àwọn olùdarí méjì tí ó gbégbá orókè níbi ìpele àkọ́kọ́ ìdìbò Ààrẹ ọdún 2022.

Gẹgẹ bi esi idibo alakọkọ ti o waye  ni ọjọ aiku, awọn oludari meji ni idaa mejidin-lọgbọn o le diẹ  ati ida mẹtale-logun o le diẹ ibo ni sisẹntẹle.

Aarẹ Macron bura lati ṣe imuse iṣẹ akanṣe,ati lati mu ilọsiwaju Faranse ati Yuroopu gba ominira,eyi ti o ṣe adehun fun.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button