Take a fresh look at your lifestyle.

Shanghai pinnu láti fìyà jẹ ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sófin ìgbélé ààrùn còrónà

Olú-ìlú ìṣòwò orílè-èdè Ṣáínà ní Shanghai  ti kìlọ̀ pé ẹnikẹ́ni tí ó bá rú àwọn òfin ìgbélé ààrùn còrónà  yóò jẹyán ẹ̀ níṣu. Ẹka ọlọpa ilu ṣalaye awọn ihamọ ti pupọ ninu awọn olugbe mẹedọgbọn miliọnu  …

Ìpànìyàn Plateau: Ààrẹ Bùhárí ní ẹlẹ́ṣẹ̀ kan kò ní lọ láìjìyà

Bí àwọn àlàyé kíkún ṣe jáde lórí àwọn ìkọlù oníjàgídíjàgan tí ó burújàì ní agbègbè Kanam àti Wase ní Ìpínlẹ̀ Plateau, Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti ṣe àpèjúwe ìpànìyàn náà bíi ìwà búburú,tí…

Àwọn afẹ̀hónúhàn orílẹ̀-èdè Tùnísíà Kọ ìjọba Ààrẹ Saied

Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Tùnísíà ṣe àpèjọ ní olú ìlú Túnísìì, láti fi òpin sí ohun tí wọ́n ṣe àpèjúwe rẹ gẹ́gẹ́ bí fífipá gba agbára lọ́wọ́  Ààrẹ wọn, Kais Saied. Ẹgbẹ kan ti a npè ni “Awọn ara ilu…
button