Take a fresh look at your lifestyle.

Shanghai pinnu láti fìyà jẹ ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sófin ìgbélé ààrùn còrónà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 204

Olú-ìlú ìṣòwò orílè-èdè Ṣáínà ní Shanghai  ti kìlọ̀ pé ẹnikẹ́ni tí ó bá rú àwọn òfin ìgbélé ààrùn còrónà  yóò jẹyán ẹ̀ níṣu.

Ẹka ọlọpa ilu ṣalaye awọn ihamọ ti pupọ ninu awọn olugbe mẹedọgbọn miliọnu  nkọju  ati pe wọn lati gbogun ti ajakale-arun naa pẹlu ọkan kan ati ifọwọsowọpọ fun aṣeyọri.

Ọlọpa Shanghai tun fi ofin de awọn ọkọ ayọkẹlẹ ayafi awọn o ni ipa ninu iṣẹ idena ajakale-arun tabi gbigbe awọn eniyan ti o nilo itọju ilera pajawiri.

Leave A Reply

Your email address will not be published.