Take a fresh look at your lifestyle.

NIS yóò lo Àwọn agbègbè ìbílẹ̀ Láti Ṣàyẹ̀wò arúfiin ìrìnàjò

Láti ri pé àjọṣepọ̀ tó dánmọ́rán wà láàrin àwọn agbègbè ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Cross River, gúsù-gúsù Nàìjíríà,ìgbìmọ̀ tó ń mójútó ètò ìrìnàjò ní  Nàìjíríà, NIS, tí ń ṣe ìpolongo fún àwọn…

Àyíká Àìléwu: Àjo Ààbò Àgbáyé fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Àgùnbánirọ̀, NYSC

Àjọ Ààbò Àgbáyé, (WSO) ti fọwọ́ sí ìwé àdéhùn tí ó yẹ pẹ̀lú Àgùnbánirọ̀, NYSC, láti ṣe ìtanijí lórí ìhùwàsí ìgbé ayé àìléwu àti àyíká fún gbogbo àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Aarẹ ajọ ọhun,…

Ètò Ìpèsè oúnjẹ fún Ilé-ìwé Ṣe àlékún Ìforúkọsílẹ̀ akẹ́kọ̀ọ́ jákèjádò…

Àjọ Àgbáyé tó ń rísí Ètò Oúnje  (WFP) sọ pé Ètò fífún Ilé-ìwé l’óúnjẹ ọ̀gbìn Orílẹ̀-èdè (NHGSFP) ti jẹ́ kí àwọn tó ń kàwé pọ̀ si jákèjádò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Gẹgẹ bi Eto Ounjẹ Agbaye 2021,…

Mi ò ní yí padà kúrò lórí ìlànà bí wọ́n ṣe ń jẹ olúbàdàn -Ṣèyí Mákindé

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé ṣe àbẹ̀wò ẹkú araá-fẹ́ra kù sí opó Ọba Sálíù Adétúnjí, Ajéogungun I, Olúbádàn ti ìlú Ìbàdàn tí ó sì fi àsìkò ọ̀hún sèlérí pé ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ yóò ṣe ayẹyẹ…

Títọ́ka sí àwọn adigunjalè gẹ́gẹ́ bíi ọ̀daràn yóò mú ìyípadà bá Àwọn ilé-iṣẹ́…

Títọ́ka sí àwọn ọlọ́ṣà gẹ́gẹ́ bí oníjàgídíjàgan yóò ki àwọn ilé-iṣẹ́ ààbò Nàìjíríà láyà láti gbógun ti  àwọn oníṣẹ́ ọ̀daràn. Ni orukọ alakoso ẹgbẹ Naijiria, All Progressives Congress, APC, Akọwe Abojuto ẹgbẹ…
button