Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ènìyàn mọ́kànlé-lọ́òdúnrún míràn tún ti kó ààr̀un còrónà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 88

Àwọn ènìyàn mọ́kànlé-lọ́ọ̀dúnrún mírán tún ti ní ààrùn còrónà.
Ile-iṣe to n mujuto ajakalẹ aarun ni orilẹ-ede Naijiria (NCDC) ,lo sọ eleyi di mimọ lorii boṣe n lọ.
Awọn eniyan wọnyii jẹyọ lati ipinlẹ mẹwa.
Ipinlẹ Eko – marundin-lọgọsan, Ondo-mejile-logoji, Osun-mẹtale-logun, Rivers-mọkanle-logun, Nasarawa-mẹrindin-logun, Oyo-ẹjọ, Gombe-meje, Kaduna-meje, FCT-ẹyọkan, Kano-ẹyọkan.
Lọwọlọwọ bayii,eniyan ẹgbẹ́rún- le- ni -ọ̀kẹ́- méjìlá- abo- o –din- ni- ẹ̀sán- din – lọ́rin lo ti ni aarun ọhun, ẹgbàájì- le- ni- ọ̀kẹ́- mọ̀kànlá- o- le- ni- ẹ̀jọ- din– lọ́ta eniyan ti gba iwosan ti ẹ̀ta- le- ni -ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ẹ̀rìndínlógún si ti jẹpe oluwa.

Leave A Reply

Your email address will not be published.