Shanghai pinnu láti fìyà jẹ ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sófin ìgbélé ààrùn còrónà
Olú-ìlú ìṣòwò orílè-èdè Ṣáínà ní Shanghai ti kìlọ̀ pé ẹnikẹ́ni tí ó bá rú àwọn òfin ìgbélé ààrùn còrónà yóò jẹyán ẹ̀ níṣu.
Ẹka ọlọpa ilu ṣalaye awọn ihamọ ti pupọ ninu awọn olugbe mẹedọgbọn miliọnu …