Ìwọlé Ọdún 2022: Èsì ìdánwò jáde
Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́, Àdàmú Àdàmú ti kéde àbàjáde èsì ìdánwò Ìwọlé àpapọ̀ orílẹ̀-èdè ti ọdún 2022, sí àwọn ilé-ìwé girama ìjọba àpapọ̀ mẹ́rìnlá-lé-lọ́gọ̀rún káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.…