Ibo Equatorial Guinea: Teodoro Obiang Jáwe Olubori L’ẹlẹ Kẹfà
Àwọn Olùṣàkóso Ibo Equatorial Guinea tì kéde Teodoro Obiang Nguema Mbasogo gẹ́gẹ́ bí Olubori ìbò Ààrẹ ní ẹlẹ́kẹfà.
Ẹní Ọgọrin Ọdún yii ti wá lórí àlééfa láti ọdún 1979, Ádárì ìbò ní ó Jáwe Olubori pẹ̀lú ìdá…