Ìjọba Ipinlẹ Ọ̀yọ́ ní ìlú Ìbàdàn tíì àwọn ilé ìtajá àti ilé gbígbé kàn pá nítorí ìwà ọbùn àti ìdọ̀tí wọn.
Kọmiṣọna fún èéto ààbò àti àlùmọ́ọ́nì ilẹ̀, Ọgbẹ́ní Àbíọdún Òní, ṣàlàyé bí àwọn ilé ìta-ọjà àti ilé gbígbé tí ọ̀rọ̀ yí ṣẹwò mọ, ṣé rú Ofín àipa imọtótó mọ.
Nígbà tí Agbani-nímọ̀ràn lórí Àgbègbè, Ademọlà Aderinto ń gbá ẹnu Kọmiṣọna sọrọ, Ó ní wọ́n tíì àwọn ilé wọ́nyí pa, nígbà ti Ipinlẹ wọ́n ń ṣé ìmúṣẹ àti ìpolongo àyàjọ Ìmọtótó làgbàye, làti dènà Ajákálẹ́ Àrùn nínú Ọjà, wọ́n tún lo láti dáa àwọn Ìyá Ọlọ́jàá lẹ̀kọ́ láti jẹ kí wọn mọ̀ pé Ìmọtótó ní ń borí Àrùn gẹgẹ bii Ọyẹ ṣé ń borí Òru.
Àwọn àti àwọn Ilé ìṣẹ Akolẹ ìpínlẹ Ọ̀yọ́ ní wọn jọ ṣe agbateru ìpolongo yìí ni Ọjà Akádẹ́mì, Ìbàdàn.
Leave a Reply