Take a fresh look at your lifestyle.

Biden Olórí Àgbáyé Yóò Wa Níbí Ìsìnkú Ọbabìnrin Elizabeth

0 56
Ààrẹ Orílẹ-èdè Amẹrika, Joe Biden, awọn bí Ẹẹdẹgbẹ̀tá Àwọn Olórí ìjọba Ipinlẹ àti àwọn ènìyàn jàǹkàn-jàǹkàn ní ilẹ̀ Okere ni wọ́n yóò wá níbí ìsìnkú Ọbabìnrin Elizabeth II ni ọjọ́ Aje eyi ti yóò fún ìkójọpọ awọn Olori Àgbàye tí wọ́n ti rírà gbẹ̀yìn fún àìmọye Ọdún ni àǹfààní láti pàdé.

 

Ọgbẹ́ní Biden, Ààrẹ Kanada, Justin Trudeau; Australia, Anthony Albanese ati New Zealand, Jacinda Ardern ní wọ́n tí wá ni UK. Awọn Ààrẹ wọ̀nyí kò gbẹ̀yìn – tí  Bangladeshi – Sheikh Hasina, Sri Lankan – Ranil Wickremesinghe, Ààrẹ Droupadi Murmu ni yóò máa sójú India, Ilẹ̀ Faransé – Emmanuel Macron, Irish – Taoiseach Micheal Martin, Jámánì; Frank-Walter Steinmeier, ati Itali – Sergio Mattarella.  Awọn idile Ọba jákèjádò Ilu Òyìnbó.

 

Tító Lọwọọwọ
Gbọngan Westminster ni ayẹyẹ yí yóò ti wáyé láti fún Ọbabìnrin ní èéto ayẹyẹ ìkẹyìn ti wọ́n yóò sì máa fí ọwọ sínú ìwé ìkẹdùn ní Òrùlé Lancaster.

 

Ọba Charles III yóò máa ṣe ayẹyẹ ìgbà àlejò ní Ọjọ́ Àìkú ni Ààfin Buckingham.  Èéto ìsìnkú yí, ní yóò fún ọpọlọpọ Àwọn Olórí ní ànfààní láti jíròrò lórí ìṣèlú.
Leave A Reply

Your email address will not be published.