Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbógunti Dídá Abẹ Fún Ọmọbinrin, Ìdẹ́yẹsí Àti Àṣìlò Ọmọbinrin: Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fi Ìgbìmọ̀…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti yan ìgbìmọ̀ ti yóò máa mójú tó ìgbógunti gbogbo ọ̀rọ̀ tó níí ṣe pẹ̀lú ìdẹ́yẹsí àti àṣìlò ọmọbinrin ni Ìpínlẹ̀ náà. Ètò eléyìí to n ṣe àyajọ́ ọjọ́ ìdẹ́kun sí dídá abẹ́ fún ọmọbinrin lágbayé (International Day of…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kẹ́dùn Ikú Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀, Onímọ̀ Ẹ̀rọ Sunday Makinde

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti kẹ́dùn ikú ẹ̀gbọ́n rẹ̀, Onímọ̀ Ẹ̀rọ Sunday Makinde. Àtẹ̀jade ti Oludamọran fún Gómìnà lórí ìròyìn, Suleimon Olanrewaju fi síta fún àwọn oníròyìn ní ìlú Ìbàdàn tíì ṣe Olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ni Ẹkùn…

Ìsìn Ìdúpẹ́ Ọlọ́dọọ́dún: Makinde Ṣèlérí Àgbéyẹ̀wò Owó Òṣìṣẹ́-fẹ̀yìntì Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí láti ṣe àgbéyẹ̀wò àti láti san àwọn àjẹsẹ́yìn owó òṣìṣẹ́-fẹ̀yìntì. Bákan náà Makinde tun ṣèlérí láti rí dájú pé ìwà janduku àti àwọn ìwà burúkú míràn di àfìsẹ́yìn ti eégún n fiṣọ, nígbà tó ké…

Ọdún 2025: Ìṣèjọba Mi Yóò Mu Ìrọ̀rùn Bá Ọrọ̀ Ajé Àwọn Ènìyàn – Makinde

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí láti mú ìrọ̀rùn dé bá àwọn ènìyàn ní ọdún 2025. Makinde fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ìṣèjọba òun yóò gún le àwọn ìgbésẹ eléyìí tí yoo mu kí ìrọ̀rùn dé bá ètò ìṣúná àti ètò ọrọ̀ ajé àwọn ènìyàn Ìpínlẹ̀…

Ààrẹ Tinubu túnbọ̀ fìdí ìpinnu ìṣedéédé lórí àtúnṣe owó orí múlẹ̀

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti túnbọ̀ fìdí bí ìjọba rẹ̀ ṣe ṣe ìpinnu láti máá fìgbá kan bọ̀kan nínú àti l̀ṣètọ́ lórí ìṣètò òfin owó orí fún àǹfààní àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Aarẹ ti pa laṣẹ fun ile iṣẹ ijọba apapọ fun Idajọ lati fọwọ…

Makinde Bá Ààrẹ Tinubu Kẹ́dùn Ikú Ọgá Àgbà Ọmọ Ogun Orilẹ Èdè Nàìjíríà

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ba Ààrẹ Bọla Tinubu, Ilé Iṣẹ́ Ọmọ Ológun, àti ìjọba Ìpínlè Ọ̀ṣun kẹ́dùn ikú Ọ̀gá ọmọ ológun Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Makinde ló ti fi ikú ọga ọmọ ológun Taoreed Abiodun Lagbaja wé àdánù nlá fún Orílẹ̀…
button