Adarí orílẹ̀ èdè Nàíjíríà kẹ́dùn ikú ọgagun Zirkusu
Inú aarẹ orilẹ orilẹ ede Naijiria, Muhammadu Buhari bàjẹ́ lati gbọ́ ikú ọgagun Dzarma Zirkusu ati awọm ikọ ọmọ ogun mẹta to padanu ẹ̀mí wọn lasiko ti wọn n daabo bo isọkan ati ààbò orilẹ ede Naijria nipa síse ìkọlù si ikọ ọmọ…