Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari Jíròrò Pẹ̀lu Àwọn Olùdókòwo

109

Nínú ìjíròrò pẹ̀lú àwọn olùdókòwò, Ààrẹ Buhari fi dá wọn lójú pé, ìdókòwò lórí gaasi ló jẹ Nàìjíríà lógún jù, nítorí  àwọn àǹfààní tó rọ̀ mọ.

Nigbati o n ba alakoso Total, Patrick Pouyanne sọrọ; Aarẹ ṣe akiyesi pe Naijiria ti ṣe awọn idoko-owo to jọju lori gaasi, ati pe wọn o ni sinmi lati maa ṣe eyi, ki wọn le dekun awon eefi to le ṣe eniyan ni jamba.

Leave A Reply

Your email address will not be published.