Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Nàìjíríà Nílò Ògùn Corona Si

115

Ní ọjọ́ Ọjọ́bọ̀, ní ìlú Paris, orílẹ̀ – èdè Faranse ni Ààrẹ Buhari ti gba àwọn olórí, ààrẹ àti gbogbo ilé-iṣé tó ń mójútó ìlera ní mòràn láti pèsè ògùn corona lọ́pọ̀ fún àwọn ará ìlú.

O tesiwaju, o sọ pe, ti ogun yi o ba lọ kari gbogbo orilẹ-ede, bi ẹni to da omi sapẹrẹ ni o; nitori wipe eyi yoo mu ewu ba awọn orilẹ-ede yooku.

Aarẹ Buhari dupẹ lọwọ awọn orilẹ-ede bi Faranse, ti o sinmi lati ri wipe ogun yi lu jaye kara.

Leave A Reply

Your email address will not be published.