Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Oyo fọwọ́ sí Àdéhùn Pẹ̀lú ilé Iṣẹ́ iṣẹ́ Agbára

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Oyo, nípasẹ̀ Ilé Iṣẹ́ Àyíká àti Àwọn Ohun Àdánidá, ti fọwọ́ sí àdéhùn pàtàkì kan pẹ̀lú ilé iṣẹ́ agbára kan, tí a fẹ́ mú kí àwọn ètò àti ìlànà ojúọjọ́ rẹ̀ lágbára sí i, tí ó dojúkọ ìṣàkóso àyíká Kọmíṣọ́nà fún Àyíká àti Àwọn…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣe Ètò Láti Mú Ki Ọ̀gbìn Iṣu gbòrò Sí 

Ìjọba Nàìjíríà ti ṣí Ètò Ìdàgbàsókè láti mú kí ìṣẹ́ àgbẹ̀ tí ni gbórò sí pàápàá jùlọ ọgbin isu láti ìwọ̀n tọ́ọ̀nù mẹ́wàá sí ìwọ̀n tọ́ọ̀nù mẹ́ta fún hektari kan. Ètò náà jẹ́ ara ètò ìyípadà iṣẹ́ àgbẹ̀ tí a ṣe láti mú kí owó ìṣẹ́ àgbẹ̀ tu…

Ìpínlẹ̀ Kano, Àjọ Pàtàkì  Fún Ètò Imototo Ati Fifọ Ọwọ́ (WASH) Ṣe Àgbékalẹ̀  Ètò Náà Ni Ìpínlẹ̀ Kano

Wọ́n ti ṣe àgbékalẹ̀ àǹfààní sí àwọn iṣẹ́ omi, ìmọ́tótó  ní àwọn apá kan ní Ìpínlẹ̀ Kano lẹ́yìn àwọn ìtọ́jú tí ó dúró  nípasẹ̀ Self Help Africa lábẹ́ ètò WASH rẹ̀. Wọ́n tẹnu mọ́ ìdàgbàsókè náà nígbà Ìdánilẹ́kọ̀ọ́  ètò WASH àti ìrìn àjò…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti  Orílẹ̀-èdè Jámánì Ṣèlérí Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Nínú Agbára, Ààbò, Àti Ọ̀nà ojú…

Ààrẹ Bola Tinubu àti Aláṣẹ Orílẹ̀-èdè Jámánì Friedrich Merz ti pinnu láti mú kí àjọṣepọ̀ àárín gbùngbùn lágbára sí i àti láti mú kí àjọṣepọ̀ pọ̀ sí i nínú ààbò, agbára, àti àwọn ẹ̀ka ọkọ̀ ojú irin. Nínú ìjíròrò lórí tẹlifóònù, àwọn olórí…

Ààrẹ Tinubu Yan Gómìnà ìpínlẹ̀ Gombe Gẹ́gẹ́ Bí Aṣojú Ìrètí Tuntun Àti Akọ̀wé

Ààrẹ Bola Tinubu ti yan Gómìnà Ìpínlẹ̀ Gombe, Muhammadu Yahaya, gẹ́gẹ́ bí Aṣojú Ìrètí Tuntun àti Akọ̀wẹ́ fún Ìrànlọ́wọ́ Ẹgbẹ́, Ìbáṣepọ̀ àti Ìṣíṣẹ́. Ìyàn náà wà nínú lẹ́tà kan tí Ààrẹ fọwọ́ sí, tí ó pàṣẹ fún Gómìnà Yahaya láti gba àwọn…

Àjọ NIMC Yóò Bẹ̀rẹ̀ Ìforúkọsílẹ̀ Ní gbogbo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Pátá.

Ìgbìmọ̀ Ìṣàkóso Ìdánimọ̀ ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NIMC), sọ wí pé ó ti múra tán láti bẹ̀rẹ̀ ìforúkọsílẹ̀ ní ìpele gbogbo orílẹ̀-èdè  Nàìjíríà fún ìforúkọsílẹ̀ Nọ́mbà Ìdánimọ̀  (NIN) ní ìbámu pẹ̀lú àṣẹ Ààrẹ tí ó pàṣẹ fún Ìgbìmọ̀ Ìṣàkóso…
button