Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí kési àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, nílé àti ní òkèèrè, látí ṣé àtìlẹ́yìn fún ìkọ Super Eagles.
Ààrẹ náà tún tí pàṣẹ fún Ìgbákejì rẹ̀ Kashim Shettima látí darí àwọn ẹgbẹ́ àlátìlẹ́yìn kàn lọ́ sí ibí ìparí ‘African Cup of Nations (AFCON) 2023’ ní Côte d’Ivoire.
President Bola Ahmed Tinubu @officialABAT has tasked Vice President Kashim Shettima @KashimSM with leading a presidential delegation to the #AFCON finals in Côte d'Ivoire.
VP Shettima, representing the President at the semi-finals, witnessed the Super Eagles' victory over South… pic.twitter.com/6Bc8DgMHks
— Voice of Nigeria (@voiceofnigeria) February 10, 2024
Ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ààrẹ ṣé ìtọ́sọ́nà náà nínú àlàyé kàn tí Olùrànlọwọ Pàtàkì rẹ̀ lórí ètò ìròyìn àti ibanisọrọ, Stanley Nkwocha fowosi nipasẹ.
Ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò kojú orílẹ̀-èdè Côte d’Ivoire nínú ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ aṣe kagbá ní pápá ìṣèré Alassane Ouattara ní Abidjan ní ọjọ́ Àìkú, ọjọ́ Kọkànlá, oṣù Kejì.
Ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ náà yóò ṣé ìrántí bí Nàìjíríà ṣé bóri Côte d’Ivoire pẹ̀lú àmì ayò kàn sí odo (1-0) látí ẹ̀sẹ̀ William Troost-Ekong.