AFCON 2023: Ààrẹ Nàìjíríà Bèèrè Fún Àtìlẹ́yìn Ìkọ Super Eagles
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí kési àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, nílé àti ní òkèèrè, látí ṣé àtìlẹ́yìn fún ìkọ Super Eagles.
Ààrẹ náà tún tí pàṣẹ fún Ìgbákejì rẹ̀ Kashim Shettima látí darí àwọn ẹgbẹ́ àlátìlẹ́yìn kàn lọ́ sí ibí ìparí…