Take a fresh look at your lifestyle.

NECO Sún Ìdánwò Ìgbéga Àwọn Òṣìṣẹ́ Rẹ̀ Síwájú Láì Lọjọ́ Túntún

248

Àwọn Alàkóso tí Àjọ Ìdánwò tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NECO) tí kéde ìdádúró àlai lọjọ́ tí ìdánwò ìgbéga àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ tí ọdún 2024 tó yẹ́ kó wáyé ní ọjọ́ kẹ́rinlá sí ọjọ́ kẹ̀ẹ́dogún (14th and 15th) Oṣù Kéjì ọdún yìí ní Minna, Ìpínlẹ̀ Niger.

Èyí wà nínú àlàyé tí Adele Olùdarí, Ìròyìn àti Àlàyé tí Ìbáraẹnisọ̀rọ̀, Azeez Sani

Gẹ́gẹ́ bí o tí sọ, ìdádúró náà wá ní ìbámu pẹ̀lú ìtọ́sọ́nà tí Ìgbìmọ̀ lórí Àwọn ẹgbẹ́ Ìdánwò abẹle tí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú sí alága ìgbìmọ̀ náà, Oboku Abonsizibe Oforji buwọ́lù.

Sani sọ pé pẹ̀lú ìdàgbàsókè yìí, gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ NECO tó yẹ́ kí ó ṣé ìdánwò ìgbéga náà ní ọdún yìí ní wọ́n tí sún síwájú láì lọjọ́ túntún mìíràn.

Comments are closed.

button