Ààrẹ Muhammadu Buhari ti fi dá ajọ awọn oludasilẹ ile-isẹ ti Nàìjíríà (MAN) lójú pé ijọba Nàìjíríà yóò gbé àwọn ìgbésẹ̀ tó yẹ láti mú kí àyè gba lilo owó ilẹ̀ okèèrè fún gbígbé àwọn ohun èlò àti ẹ̀rọ tí kò sí ni Naijiria wole.
O ṣe adehun naa ni ilu Abuja ni Ọjọ Ọjọrú, lakoko ibẹwo awọn olori MAN, ni idahun si ibeere lori jijẹ ki ẹka idasile o ko ipa to joju ninu ọrọ aje Naijiria
Leave a Reply