Take a fresh look at your lifestyle.

2023: INEC pèsè Àwọn Ilé Ìforúkọ sílẹ̀ olùdìbò mẹ́rìnlá si ní Àbújá

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 340

Ìgbìmọ̀ olómìnira tó ń mójútó ètò Ìdìbò   lórílẹ̀-èdè, INEC, ti pèsè àwọn ibùdó tí àwọn olùdìbò ti le máa forúkọ sílẹ̀ mẹ́rìnlá mìíràn (CVR), ní olú-ìlú, Àbújá, láti kojú ìtúyáyá àwọn olùforúkọ sílẹ̀.

INEC sọ eyi ninu ọrọ kan to wa lati ọdọ kọmisọna  INEC ti olu-ilu, Yahaya Bello, ni ọjọ iṣẹgun, ni Abuja.

Bello sọ pe igbimọ naa tun ti ko awọn ẹrọ igborukọ awọn oludibo ti INEC aadọta si awọn ile iforukọsilẹ titun ni agbegbe naa.

O sọ pe,wọn ṣe ipese awọn ile iforukọ silẹ naa  lati le gba ọpọlọpọ eniyan ti o fẹ forukọ silẹ ni olu-ilu laye.

Awọn ibudo naa ni,

  1. City Centre–Diplomatic Park, Area 1.
  2. Gwarinpa G.S.S Life Camp.
  3. Wuse G.S.S Zone 3.
  4. Kabusa Primary School and Lugbe Primary School.

 

  1. Giwa-Gwagwa Primary School.
  2. GUI-Gosa Primary School.
  3. Karshi-Karshi Development Center. 8. Orozo=Orozo Primary School.

Awọn yooku ni:

  1. Nyanya-G.S.S Nyanya.
  2. Kubwa-L.E. A Primary School Kubwa.
  3. Dutse-Alhaji-L.E. A Primary School Dutse,
  4. L.E. A Primary School, Dawaki
  5. L.E. A and Primary School, Mpape.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button