Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdùnnú ṣubú layọ̀ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù Flying Eagles

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 280

Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù  Nàìjíríà ti ́ kò ju ogún ọdún lọ Flying Eagles, ti pegedé Fún ìdíje ife ẹ̀yẹ adúláwọ̀ 2023,pẹ̀lú àmì ayò méjì sí ọ̀kan fún orílẹ̀-èdè Ivory Coast, fún ìdí èyí, ó ti kójú òsùnwọ̀n fún ìdíje ife ẹ̀yẹ adúláwọ̀, {AFCON},ní Égípítì

Nàìjíríà yóò máa dojú kọ orílẹ̀-èdè Benin báyìí nínú àṣekágbá ìdíje ẹkùn náà ní ọjọ́ ẹtì, ogúnjọ́, oṣù karùn-ún.

Ọrilẹ-ede Naijiria ni anfaani lati  gba ami ayo wọle lọpọlọpọ igba,sugbọn aṣọju awọn wọn kunju osunwọn. Sibẹsibẹ, idije naa pari ni amin kọọkan ti yoo si pan dandan lati fun wọn ni akoko afikun tabi gbasimi n gbasiọ.

Ibrahim Yahaya gba ami ayo wọle ni idaji keji ti akoko afikun leyi ti o mu Naijiria siwaju. Bi o tilẹ jẹ wi pe awọn ọmọ orilẹ-ede Ivory Coast n halẹ lati dọgba, sibẹsibẹ, ifẹsẹwọnsẹ naa pari pẹlu ami ayo meji si ọkan,ti Naijiria si jawe olubori.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button