2023: ‘Àwọn ọ̀dọ́ le Yí Orílè-èdè padà sí dáradára’ – Olùdíje fún ipò ààrẹ
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Olùdíje fún ipò Aàrẹ lábẹ́ àsìá Accord, Aṣojú Dọ́kítà Solomon Uchenna Wining, ti sọ pé àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà ní gbogbo nǹkan tí ó gbà láti yí orílẹ̀-èdè padà kúrò nípò tí ó wà lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, tí yóò sì jẹ́ ìṣedédé pèlú àwọn orílẹ̀-èdè tí ó ti lajú.
Dókítà Wining sọ èyí di mímọ̀ nígbà tó ń bá àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀ níbi ìparí ìpàdé rẹ̀ pẹ̀lú àwọn alága ètò àjọ náà ní ìpínlẹ̀ márùn-ún ní ẹkùn Gúúsù Ìlà Oòrùn nílùú Owerri, ní ìpínlẹ̀ Imo.
O ni orilẹ-ede yii wa ni ipo ti o wa loni yii nitori pe awọn aṣaaju iṣaaju ti kuna lati fi ara wọn silẹ fun idagbasoke orilẹ-ede
Leave a Reply