Láti ri pé àjọṣepọ̀ tó dánmọ́rán wà láàrin àwọn agbègbè ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Cross River, gúsù-gúsù Nàìjíríà,ìgbìmọ̀ tó ń mójútó ètò ìrìnàjò ní Nàìjíríà, NIS, tí ń ṣe ìpolongo fún àwọn aṣaájú ìbílẹ̀ àti ẹ̀sìn lórí pàtàkì pípa àwọn òfin àti ìlànà ìrìnàjò mọ̀.
Ọludari eto irin ajo,ti ipinlẹ Cross River, Ọgbẹni Christopher Baikie, sọ eyi di mimọ lakoko ifọrọjomitoro ọrọ pẹlu awọn oniroyin kan ni Calabar, olu-ilu ipinlẹ naa.
Baikie, pẹlu awọn ọga agba to wa labẹ asẹ naa, so pe ajo NIS “ti mu gẹgẹ bii ojuse lati kan si awon ọmọ agbegbe bii Obong ti Calabar, Eze Ekpo Okon Abasi Otu, Karun ati awon mi-in. . A ti bẹrẹ itaniji lati ni ibaṣepọ to danmọran pẹlu awọn eniyan.
Leave a Reply