Ààre Mùhámmádù Bùhárí ń darí ìpàdé Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ lórí ayélujára ní yàrá àpèjọ ti ọ́fíísì Ìyáàfin àkọ́kọ́,ní Ilé Ìpínlẹ̀ Àbújá.
Igbakeji Aarẹ Yẹmi ọsinbajo, Akọwe fun ijọba apapọ, Boss Mustapha ati ọga agba fun awọn Oṣiṣẹ fun Aarẹ, ọjọgbọn Ibrahim Gambari wa lara awọn ti o wa nijoko nibi ipade naa, eyiti o bẹrẹ ni agogo mẹsan an owurọ.
Lara awon to tun wa nibi apejọ naa ni minisita fun eto iroyin ati asa, Lai Mohammed; ọga agba adajọ ti o tun jẹ Minisita fun Idajọ, Abubakar Malami; Isuna, inawo ati eto orilẹ-ede, Zainab Ahmed ati Awọn orisun omi, Suleiman Adamu.
Awọn yooku ni minisita; ọkọ ofurufu, Hadi Sirika, olu-ilu, Mohammed Bello, lilọ bibọ, Rotimi Amaechi, ọrọ abẹle, Rauf Aregbeshola ati Minisita ti Ipinlẹ fun ẹto ẹkọ, Chukwuemeka Nwajiuba.
Olori fun awọn oṣisẹ orile-ede lapapọ , Folashade Yẹmi-Ẹsan ati awọn minisita miiran n kopa lati awọn ọfiisi wọn ni Abuja.
Awọn alaye Nigbamii…….
Leave a Reply