Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí bá ọ̀jọ̀gbọ́n Gambari kú oríire ọdún kẹtàdín-lọ́gọ́rin

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

62

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí àti àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin  kí Olórí  awọn Òṣìṣẹ́ rẹ̀, Ọ̀jọ̀gbọ́n Ibrahim Agboọlá Gambari kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún mẹ́tàdínlọ́gọ́rin.

Ki  ipade   Igbimọ Alaṣẹ apapọ to bẹrẹ, Akọwe  fun Ijọba  apapọ, Boss Mustapha kede ọjọ ibii  minisita naa fun wọn.

Ọjọgbọn Gambari darapọ mọ ijọba gẹgẹ bi ọga agba fun awọn Oṣiṣẹ ni ogun oṣu  sẹyin, lẹyin iku Abba Kyari ti o wa nipo naa tẹlẹ

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.