Olùdarí àjọ Fisheries and Aquaculture Business Development Agency (FABDA), Emeka Illoghalu, ti Ìpínlè Anambra ti pè fún àtúnṣe ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn ní gbogbo ìpínlẹ̀ àti ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lápapọ̀ ní wàrànsesà. Eléyìí yóò mú kí àwọn olùdásílẹ̀ iṣẹ́ ògbìn àti àjọ SME kí wọ́n leè se dáradára.
Ó sọ síwájú pé kí ìjọba ró ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn lágbára ki ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìmọ̀ tí a ní lẹ́ka ètò ọ̀gbìn má bà sọnù, gẹ́gẹ́ bí ìpínlẹ̀ Anambra ti ṣe báyìí nípasẹ̀ ìdásílẹ̀ àjọ Fisheries and Aquaculture Business Development Agency (FABDA).
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply