Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Kano ṣèpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Tinubu

Eyitayọ Fauziat OYetunji

11

Gómìnà ipinlẹ Kano, Abba Yusuf, ti ṣèpàdé pẹ̀lú Ààrẹ Bọla Tinubu ní ilé iṣẹ́ Ààrẹ, Villa, Abuja, olú ìlú Nàìjíríà.

Ipade bonkẹlẹ yii waye lori boya Gomina Yusuf fẹ kuro ninu ẹgbẹ to wa, Nigeria People’s Party (NNPP),  leyi ti wọn ti dibo yan an ni Gomina, lọ si ẹgbẹ All Progressives Congress (APC).

A o ranti pe Alaga gbogbogboo ẹgbẹ NNPP, Sẹnetọ Rabiu Kwankwaso, ti da ijabọ pe oun ti fọwọsi igbesẹ Gomina ipinlẹ Kano lati kuro ninu ẹgbẹ naa nu, ti o si ni kosi nnkan to jọ bẹẹ.

Ẹkunrẹrẹ lori ipade naa yoo jẹyọ laipẹ.

Comments are closed.

button