Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Múlele Lórí Ìwúlò Àjọṣepọ̀ Ilẹ̀ Òkéere Fún Ìtèsíwájú Ẹ̀ka Ètò Ìwakùsà

120

 

Ìgbákejì pataki nípa iroyin sì Mínísítà ìtèsíwájú àwọn ohun alumọni ilẹ̀,Segun Tomori ló gbé eleyi síta.

 

Dókítà Alake sọ pàtàkì ojuse ìwakùsà nípa ti ìlànà agbaye ní ti àjọ Organisation for Economic Cooperation and Development (OECD) ní Paris, orílè-èdè Faransé.

Ó sọ bi o ṣe se pàtàkì láti ní ibi ti wọn fẹ́ lò tó gbajúmọ̀, ìlọsókè iṣẹ́ wọn, isakoso ohun àlòkù wọn ti kò dára abbl.

 

Mínísítà tún sọ pàtàkì ìgbésẹ̀ ní àsìkò Nàìjíríà láti nánwó si ẹka náà kí wọn le ri awon ti wọn nìfẹ́ láti kówó leè lórí kí àwọn náà sì leerí èrè tabua.

 

Fún àpẹrẹ, ni abala àkọ́kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ ọdún yìí, orílẹ̀-èdè yìí ri owó tó súnmọ́ Bílíọ̀nù méje Naira nipasẹ sise Lísẹ̀nsì owó ìwakùsà .
 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button