Take a fresh look at your lifestyle.

Gbíngbin Ìgi Fún Àjọyọ̀ Ọjọ́ìbí Àti Ọdún Tuntun Mú Ìyí Wa Púpò : Ẹgbẹ́ NCF.

58

Adari àgbà pátápátá fún ẹgbẹ́ NCF, Joseph Onaja ti pé àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ma gbin igi fún Ayẹyẹ ojo-ibi, òní èyí ṣe pàtàkì jù ṣíṣe owó kumokumo ló.

Ọnaja sọ èyí di mímọ̀ ni ìlú Abuja níbi ayẹyẹ gbìn gbìn Igi to wáyé.

Ó ní nípa ìgi gbingbin àwọn anfààní to pọ wa nínú re, yóò mú atégùn àlàáfíà wa, yóò mú ètò ọ̀rọ̀ ajé dàgbà a sí dí oorun  ku láwùjọ.

Èdè Dafinone sọ wí pé ìlú Abuja ti gbé ìgbésẹ akọkọ báyìí láti bèrè sí ni gbìn Igi káàkiri.

Wọn ní ìlú Abuja ṣe n dàgbà láwọn agbègbè kan ni, tí àwón ènìyàn sí n ge ìgi Lai Se wí pé wọn gbìn àwọn ìgi náà padà, o ni èyí ko bójú rárá.

Wọn ní  ìgi gígé yóò mú agbara pósí èyí sí le fà àkóbá nlá to pọju fún gbogbo wa.

Comments are closed.

button